Olúwaṣeunàrà
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúwaṣeunàrà
The lord does wonders.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olúwa-ṣe-oun-àrà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olúwa - lord, Godṣe - make, do
oun - something
àrà - wonder
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL