Olúwátómilọ́ba
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúwátómilọ́ba
God is king enough for me.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olúwa-tó-mi-ní-ọba
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olúwa - lord, Godtó - sufficient enough for
mi - me
ní - in
ọba - kingship, royalty
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
