Olúwátẹ́tí

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwátẹ́tí

God Listens or God hears.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-tẹ́-etí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
tẹ́ - spread
etí - ears


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL