Olúwámáyọ̀mikún

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwámáyọ̀mikún

God has made my joy whole.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-mú-ayọ̀-mi-kún



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
mú - make
ayọ̀ - joy
mi - mine
kún - full, whole


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Máyọ̀kún