Olúwámáyọ̀kún

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwámáyọ̀kún

The Lord made (my) joy full.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-mú-ayọ̀-kún



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
mú - make, bring
ayọ̀ - joy
kún - full


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Olúmáyọ̀kún

Máyọ̀kún