Olúwákọ́ládé
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúwákọ́ládé
God brought honour.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olúwa-kó-ọlá-dé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olúwa - God, Lordkó - gather
ọlá - wealth, nobility, success, fortune
dé - arrive
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL