Olúwáfisádémi
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúwáfisádémi
God has added (something good) to my crown
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olúwa-fi...sí-adé-mi
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olúwa - lord, Godfi...sí - add to
adé - crown, royalty
mi - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKO