Olúwáfimíṣọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwáfimíṣọlá

God used me for fortune/success.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-fi-mí-ṣe-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
fi - use
- me
ṣe - make, create
ọlá - honour, wealth, success, notability


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA