Olúwáfarabalẹ̀dámilọ́lá

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwáfarabalẹ̀dámilọ́lá

God has intentionally arranged His blessings for me.



Àwọn àlàyé mìíràn

fi-ara-ba-ilẹ̀ or farabalẹ̀ is used as an expression to mean 'calmly', 'carefully and without hurry', or 'to calm down'.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-fi-ara-ba-ilẹ̀-dá mi-ní-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - God
fi - to put
ara - body
ba - to lay on, to touch
ilẹ̀ - floor, ground
dá mi - to gift to me, left to me
ní - of
ọlá - nobility, grace, favour, wealth


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL