Olúwádémiládéògo

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwádémiládéògo

Lord, cover me with a crown of glory.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-dé-mi-ní-adé-ògo



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
dé... l'ádé - crown
mi - me
-
adé - crown


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Démiládé