Olútọ́pẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Olútọ́pẹ́

The prominent one/the Lord is worthy of praise.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olú-tó-ọpẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olú - prominent one; Lord, God
- sufficient for; worthy of; equal to
ọpẹ́ - grace, permission, gratitude


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Olúwatọ́pẹ́

Tọ́pẹ́