Olúsúnmbáre

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúsúnmbáre

God moved me towards goodness.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olú-sún-mi-bá-ire



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olú - lord, God, the most prominent one
sún - move
mi - me
bá - together with, close to
ire - goodness


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Olúsúmbáre