Olúrónbí

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúrónbí

The prominent one has found a (good) child to birth.



Àwọn àlàyé mìíràn

Olúróunbí/Olúrónbí is a famous character in Yorùbá folklore.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olú-rí-oun-bí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olú - prominent one
rí - see, find
oun - something (someone)
bí - give birth to


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Olúróunbí