Olúníyì
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúníyì
God has honor. Greatness has honour. The prominent one has honour.
Àwọn àlàyé mìíràn
A common short form for Olúwáníyì.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olú-ní-iyì
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olú - lord/God (olúwa), prominent one, greatnessní - have
iyì - honour, regard, value
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL