Olúmúrewá

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúmúrewá

The lord brought goodness.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olú-mú-ire-wá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olú - lord (short for olúwa)
mú - bring
ire - goodness
wá - come, arrive


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OTHERS



Irúurú

Múrewá