Olúmúléró
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúmúléró
The Lord holds up the home.
Àwọn àlàyé mìíràn
See also: Akínmúléró, Oyèmúléró, Adémúléró, etc
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olú-mú-ilé-ró
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olú - the prominent one, olúwamú - hold
ilé - house, home
ró - stand (dúró)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL