Olúlánú
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúlánú
The prominent one is merciful.
Àwọn àlàyé mìíràn
More properly written as Olúláànú or even Olúláàánú.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olú-ní-àánú
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olú - prominent one; Lord, Godní - have, own; in
àánú - mercy
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL