Olúkúewu
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúkúewu
The hero be praised for escaping danger.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olú-kú-ewu
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olú - olúwa (the lord)kú - commended for
ewu - danger
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OTHERS
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
On Air Personality: Yeye Bidemi Olukuewu
otherwise known as Afedésẹwà.