Olúkìíbàátì
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúkìíbàátì
God doesn't do incomplete jobs.
Àwọn àlàyé mìíràn
Also: Olúkìíbatì
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olúwa-kìí-bàá-tì
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olúwa - lord, Godkìí - does not
bàá - touch (it)
tì - support
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL