Olúkàmíyẹ
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúkàmíyẹ
God counts me worthy.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olú-kà-mí-yẹ
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olú - prominent one, God (Olúwa)kà - read, count, consider
mí - me
yẹ - be respectable, be befitting of
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL