Olúgbádéhàn
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúgbádéhàn
1. The leader showcased (our) royalty.2. God showcased (our) royalty.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olú-gbé-adé-hàn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olú - prominent one; Lord, Godgbé - to carry, to lift
adé - crown, royalty
hàn - to appear
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL