Olúgbọ́láwá
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúgbọ́láwá
1. God brought honour to us. 2. The leader brought honour to us.
Àwọn àlàyé mìíràn
See: Olúmọ́láwa
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olú-gbé-ọlá-wá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olú - prominent one; Lord, Godgbé - to carry, to lift
ọlá - honour, prestige, wealth, nobility
wá - to find, to come
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL