Olúgbọ́lága

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúgbọ́lága

God elevated (our) honour.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olú-gbé...ga-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olú - the prominent one, olúwa
gbé...ga - elevate
ọlá - honour, grace, wealth, success, nobility


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI
IFE



Irúurú

Gbọ́lága