Olúfúnmilọ́lá
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúfúnmilọ́lá
The lord gave me wealth.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olú-fún-mi-ní-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olú - heroism, prominent one, lord (olúwa)fún - give
mi - me
ní - [particle]
ọlá - wealth
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL