Olúfisọ́lá

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúfisọ́lá

The prominent one added to wealth/nobility.



Àwọn àlàyé mìíràn

See also: Olúfisáyọ̀, Olúfisóyè, Olúfisádé



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

o-lú-fi-sí-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olú - lord, chief, olúwa, prominent one, hero
fi - put/use (it)
sí - into
ọlá - wealth, nobility


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Olúfiọ́lá