Olúdára

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúdára

HOMOGRAPH Olúdárà: The lord performs wonders. Olúdára: The lord is good.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olú-dá-àrà, olú-dára



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olú - lord, God, the champion
dá - create
àrà - wonder
-
dára - be good


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Dárà

Dára