Olúdámiláre

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúdámiláre

God has vindicated me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olú-dá-mi-ní-àre



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olú - lord, prominent one, God, leader
dá...láre - justify, vindicate
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IKARE



Irúurú

Dámiláre

Dáre

Olúwadámiláre