Olúdáìró

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúdáìró

The lord kept this one (from dying).



Àwọn àlàyé mìíràn

This is a name given to an àbíkú child. See also: Fádáìró.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olú-dá-èyí-ró



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olú - lord, God, prominent one
dá...(dú)ró - prevent from leaving
èyí - this (one)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Dáìró