Olúdáṣọrómi
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúdáṣọrómi
God covered me.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olú-dá-aṣọ-ró-mi
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olú - lord, the prominent one, the leader, prominencedá - create
aṣọ - clothes
ró - cover
mi - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL