Olúbùkúnọlámi

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúbùkúnọlámi

God has added to/increased my wealth.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olú-bùkún-ọlá-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olú - prominent one, lord, chief, olúwa
bùkún - add to, bless
ọlá - wealth, nobility
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKO