Olúbàjò

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúbàjò

The head returns from a trip.



Àwọn àlàyé mìíràn

Either as a metaphor for the return of a dead person (father, grandfather) at the time of the child's birth, or a marker of a real life return of a parent when the child was born, the name talks about journeys and its relationship to the child's life.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olú-bọ̀-àjò



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olú - lord, prominent one, olúwa
bọ̀ - return
àjò - journey


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU



Irúurú

Bàjò