Olúadùńsìn

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúadùńsìn

God (Ọlúa) is sweet to serve/worship.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-dùn-sìn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
dùn - sweet, enjoyable
sìn - worship


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI