Olùgbàlà
Sísọ síta
Ìtumọọ Olùgbàlà
Saviour.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olù-gbà-là
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olù - someonegbà - take, collect, receive, save
là - open, survive
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Assata Olùgbàlà Shakur: American civil rights leader.