Olówógbóyèga
Sísọ síta
Ìtumọọ Olówógbóyèga
The rich person elevated royalty.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olówó-gbé-oyè-ga
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olówó - a rich persongbé - carry
oyè - honor, chieftaincy ttle
ga - grow, be tall
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL