Olíyìdé

Sísọ síta



Ìtumọọ Olíyìdé

The honourable one has come.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

o-lí-iyì-dé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

o - one who
li - have (ní)
iyì - honour, dignity
dé - arrive, return


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Níyì

Oníyìdé

Olúyìdé