Olúwawámidé
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúwawámidé
God sought me out.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olúwa-wá-mi-dé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olúwa - God, Lordwá - to find
mi - me, my
dé - come, return, arrive
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL