Olúwatúsùnlé

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwatúsùnlé

God is worthy of resting upon.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-tú-sùn-lé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - God, Lord
- is worth (tó)
sùn - sleep, rest, rely
- be added to


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE



Irúurú

Túsùnlé