Olúwamúyítọ̀míwá
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúwamúyítọ̀míwá
God used this child to come and find me.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olúwa-mú-èyí-tọ̀...wá-mí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olúwa - lord, Godmú - to use; to hold (onto); to make
èyí - this one
tọ̀...wá - come to
mí - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IBADAN
IFE