Olúwafikáyọ̀mi

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwafikáyọ̀mi

God has added to my joy.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-fi-kún-ayọ̀-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
fi...kún - add to
ayọ̀ - joy, happiness
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OYO



Irúurú

Fikáyọ̀

Fikáyọ̀mi

Olúfikáyọ

Olúfikáyọ̀mi