Olúwafiayémidára
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúwafiayémidára
God is using my life to showcase his wonders.
Àwọn àlàyé mìíràn
This can also be seen as a request saying, "God, please use my life to showcase your wonders."
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olúwa-fi-ayé-mi-dá-àrà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olúwa - lord, Godfi - use, put
ayé - earth, world, life
mi - me
dá - create
àrà - wonders
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL