Olúwafọlájùwọ́n
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúwafọlájùwọ́n
God used his honor to surpass them.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olúwa-fi-ọlá-jù-wọ́n
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olúwa - lord, Godfi - used
ọlá - honour, prestige, wealth, nobility
jù - surpass, be greater than
wọ́n - them
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA