Olúwadùmílà

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwadùmílà

God struggled for me and (I) survived.



Àwọn àlàyé mìíràn

Often used by newly-converted Christians who change their names from traditional names attributed to specific Yoruba gods, such as Fádùmílà, Awódùmílà, Ògúndùmílà, etc.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-dù-mí-là



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
- struggle
- me
- to survive; to shine


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Dùmílà

Olúdùmílà