Sísọ síta
God has spared this one.
olúwa-dá...sí-èyí
Ó pọ̀ ní: EKITI
Olúwadáyísí
Dáísí
Bóyá o tiẹ̀ ní ìtàn kan láti sọ fún wa nípa orúkọ yìí, tàbí fún wa ní ǹkan tí a ṣì kọ, tàbí fikún oun kan tí a kọ sílẹ̀.