Olúwaṣeúńlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwaṣeúńlá

God does mighty things.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-ṣeun-ńlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
ṣeun - do (something we're grateful for)
ńla - big


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Olúṣeunlá

Olúṣeun

Ṣeun