Olúwátóósìn

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwátóósìn

God is worthy to be praised.



Àwọn àlàyé mìíràn

See also: Olúwatósìn



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-tó-sìn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
tó - suffice for
sìn - worship


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Olúwatósìn

Tósìn