Olúnímilọ́kàn

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúnímilọ́kàn

God has me in mind.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olú-ni-mi-ní-ọkàn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olú - lord (short for olúwa)
ní - have, own
mi - me
ní - at, in
ọkàn - mind


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OGUN