Olújẹ́nrọ́lá

Sísọ síta



Ìtumọọ Olújẹ́nrọ́lá

The prominent one allowed me to find honor.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olú-jẹ́-n-rí-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olú - prominent one; Lord, God
jẹ́ - permit, to exist, to be effective
n - me
- see, find
ọlá - success, nobility, wealth


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Jẹ́nrọ́lá