Olúgbóhùnmi

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúgbóhùnmi

The prominent one heard my voice (my prayers).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olú-gbọ́-ohùn-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olú - prominent one; Lord, God
gbọ́ - hear, listen
ohùn - voice
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Gbóhùnmi