Olúdámiláre
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúdámiláre
God has vindicated me.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olú-dá-mi-ní-àre
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olú - lord, prominent one, God, leaderdá...láre - justify, vindicate
mi - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IKARE