Olókúngboyè

Sísọ síta



Ìtumọọ Olókúngboyè

Olókun has received a chieftancy title.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olókun-gba-oyè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olókun - androgynous deity of the ocean and wealth
gba - to collect, to receive, to take
oyè - chieftaincy title, honor


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Olókún

Gboyè